[Intro]
Aii aii aii, yeah yeah yeah, Aii aii aii, yeah yeah yeah,
surulere, eko ni.
badagry, eko ni.
festac town, eko ni.
ikorodu, eko ni.
ajegunle, eko ni.
ikoyi, eko ni.
obalende, eko ni.
lelelelekki, eko ni.
QQ-QYC on the mix.
[Chorus]
oya, awon omo eko da
(awa ré)
ti eko da
(awa ré)
ti eko da
(awa ré)
ijo eko da
(oun ré)
ti eko da
(oun ré)
ti eko da
(oun ré)
ijo eko da
(oun ré)
ti eko da.
oya grind eh ko guide.
(ko guide)
oya grind eh ko guide.
(ko guide)
mo ni eh grind eh ke guide.
(ke guide)
oya grind eh ke guide
(ke guide)
[Verse 1.]
oya, awa ni’gbe to sheru ba po, shalanga ni wa, oni yeh mo ku o, edakun i lo mawu o, awon omo eko wan le ku o, ijo eko le leyi, wan ni ase mi, ase leyi, bo sen yi la, won ba yi, ah jo s’oju kan bi ba l’oya awon omo eko da, ah ya to si rebecca, ah ya to si sunmola, awon omoyiko ti eko da,
[Bridge]
wo amina, duro na, ji’ijo eko ka to lo si minna, ta ba de, ka je iyan, awon omo eko wan’ gbo na na na na.
[Chorus]
oya, awon omo eko da
(awa ré)
ti eko da
(awa ré)
ti eko da
(awa ré)
ijo eko da
(oun ré)
ti eko da
(oun ré)
ti eko da
(oun ré)
(oun ré)
ti eko da.
oya grind eh ko guide.
(ko guide)
oya grind eh ko guide.
(ko guide)
mo ni eh grind eh ke guide.
(ke guide)
oya grind eh ke guide
(ke guide)
[Verse 2.]
oya eh fly polo, oga ti de,
ka wo soke, oga wole, awon omo eko won ti de, baba lege, mo gbe de, je’n kan eh bo sen ji’jo eko, wa wale bi eni to joko, wa ma grind, wa maa guide, wa maa dance, wa maa grind, ma nogere to ba ti gbo aii, ijo ti’awon temi n’jo dubai, obe eja leleyi jo ma ro oo, ti plane o ba sare, ko ni fo oo,
[Bridge]
amina, duro na, ji’ijo eko ka to lo si minna, ta ba de, ka je iyan, awon omo eko wan’ gbo na na na na.
[Hook]
aii aii, yeah yeah,
aii aii, yeah yeah,
awon omo iyen kere si number, legely the golden son, aaaaaii,
[Verse 3.]
wo je’n gba dun lo ma gba dun, ko je’n gba dun gan o ni gba dun, awon omo eko je igbadun, but awon omo ase n’je ifo’orun, eh ba ga apa bi alagon, igboro lawa lo kan, ki’n to ma ki olu moti mo oye kan, eyin omo eko eh je kan mo.
oya grind eh ko guide.
(ko guide)
oya grind eh ko guide.
(ko guide)
mo ni eh grind eh ke guide.
(ke guide)
QYC on this one, legely the golden son.
[Chorus]
oya, awon omo eko da
(awa ré)
ti eko da
(awa ré)
ti eko da
(awa ré)
ijo eko da
(oun ré)
ti eko da
(oun ré)
ti eko da
(oun ré)
ijo eko da
(oun ré)
ti eko da.
oya grind eh ko guide.
(ko guide)
oya grind eh ko guide.
(ko guide)
mo ni eh grind eh ke guide.
(ke guide)
oya grind eh ke guide
(ke guide)
Oya!
Comments
Post a Comment